ORUKA ANASARE
AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO NINU IGBE NA TO BA JASILE AO FI NKAN KO AO LOJO PAPO AO DASI INU EPO PUPA INU EPO PUPA LAMA TIMA MU ORUKA NA. OGUN IJAKADI
Ose dudu, alubosa elewe , irun eyin olongbo dudu, tiko ni awo kankan ju dudu lo oruka ogun meji 2, koro atare meje, ao wa gun po ao wasu rugudu ao fi oruka na bo ni arin, ao wa fi aso akisa di ao lofi ha palapolo iganna (ogiri alapa tio la enu sile) fun ojo meje , ao lo mu odi lilo
IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU
Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu lofinda eyikeyi ao maa fi paa oju tabi gbogbo ara. Awon Enia yio maa ni ife waa pupo
Eseun olorun oni fin yin sile oo gbogbo nkan te ba dawole yio ma yori Si rere lase adua. Asiri yin oni tu owo yin oni kan isale apo.. Iree oo
ReplyDeleteCool and I have a swell give: How Much Home Renovation Cost home repairs contractors near me
ReplyDelete