Monday, December 2, 2024
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori fun okunrin, mefa loke mefa ni isale fun obirin ao se jina lai fi omi si ao se jina toba jina ao so si ori osuka kan ao se adura si ao bo eyin na ao je pelu adura owo leyin ojo keji o bere ise
ASIRI BIBO TODAJI
Tagiri nla meta ao ha aje ara re si ibikan ao lo aje na pelu ata ijosi meje tabi mesan fun okunrin ao fi se eja aro tabi igbin tabi eyin ibile je, pelu adura ao mu fanta mineral tutu si. odaju
fun ibere message on Whatsapp 07080271083
fun awon iwe asiri lolokan ojokan
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...
-
ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA. Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie ag...
-
ORUKA ANASARE AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO N...
-
Pdf awon acct mi fun ebun odun Moma yonda re fun gbogbo ile ni 1000 pere Sugbon akojopo agbara yoruba nikan ni 2000. 07080271083 Ori...
No comments:
Post a Comment