Thursday, August 29, 2019



                        OGUN AWISE
Ewe ina ff 7, ewe agbado ti eranko pa sile  ao ge si ona 7, irun iro, ao fi eje oromodiye lo won papo ao kosinu iwo etu ao ma fi ahon tola ti abafe soro
Ohunkohun tu aba so beni yio rio


                   OGUN ASEGBE/AJEGBE
Ewe ira, taba gidi, alubosa elewe, eku asin kan, iseta ao lowon po ao da sinu adin ao ma laa


(b).  Orogbo ki o po atare  kio po die ao ki sinu apola eran etu; ao yan yio gbe ao lo po fun lila.


                  ONMO TODAJU
Ewe isepe agbe, layonbere kan, ikode kan, eyo atare meje, ao ko won sinu layonbere ao fi aso funfun  we ao ran ni onde awo tio ba wun wa  ao ma fisi idi ni asiko tio ba wun wa pe afe mon nkan tabi afe wo ise fun customer.



                   ONMO IRIRAN  OUNJE
Ori ako alangba kan, omole kan, atare kan, ikode meta, ao bu ijalo ti nwon koja ona die ao jo gbogbo re papo ao sin ni gbere yi orun owo ka ati isale oju mejeji,ao ma sin ni osu meta meta Odaju




                     OSE OWO TODAJU (money)
Ewe taba tutu, eru alamo pupo, epo obo die, ao gun pomo ose ao ko sibi kan  ao ma buwe oda pupo fun awon oloja.










                                  

                     OSOLE OWO TODAJU
Odidi olongbo kan ao fi tele ape tagiri meta, ao ge kekeke, ap kole lori eepo obo tofe to atelewo meji ao pa pepepe, ao ko le lori ao fi odidi atare kan le ao wa ko ewe ola ti yio po ao kole lori ti yio bo ao wa ma fi oti lo lararo (shinapp) jijo ni ogun yio


                    ASEJE OWO TODAJU
ewe alukerese,ewe aje sefunsefun,epo ijebo,iyere.ao lo gbogbo re papo.ao fise edo malu je lepo niyo.(16)ni aoge edo yen si.ti oba jinnan,ao so sori osuka.awa fi iyere osun tefa ejiogbe,aope ofore si,awa dasinun obe yi ao wa je.OFORE:tente ni osu nle3×,irawo sasa nise elegbe leyin osu3×,adeyinka pele omo oloja3×,oke pele omo afegbe tinan3×,ayidi nsawo kokofa,ayidi nsawo koko ogun,odifafun orunminla nigbati awan mererin nba se ota,wan ni onifa kan kan koni wa


                OGUN OKIKI TODAJU
oga gbigbe3, ewe ewuro oojo, tio po die atare odidi kan, ao jo papo ao lo ao wa mala ao ma mu oti le lori.


2 comments:

ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER

Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...