Wednesday, August 28, 2019
ATONA/OUNMO 2 IN 1
Bibeli tuntun kan, tesibiu funfun tuntun kan, ako eye ega kan, jigi tiofo si oju ona, atare odidi kan.
SISE:- Ao mu candle funfun kan si arin bibeli ni psalm 91 ao tun mu candle blue kan si arin psalm 19ao fi amure na dini gbogbo ara ao wa fi kokoro(key) kan sin i ori nibi ti ati ma nsi bibeli latika, ao sese wa dini owu funfun dele ti bibeli na koni han sita rara
Ao sese mu blade tuntun ao fi lofa tinuteyin ilekun ti ama nsi wole dada (ilekun gbagede)
Ao lopo mo jigi oju ona na aodasi oto,
Ao sese wamu eye ega na oleje tutu tabi gbigbe, ao jusi inu ikoko tuntun pelu atare na ao jopo dada leyin ti o ba jotan ao jeki o tutu ao wa ju tesibiu na sinu re, ao gbe ikoko na pamo titi di ago kan oru (1am)
LILO:- Ao ra eko tutu, ao da awon ebu mejeji na papo ao ropo dada ao fi fo eko na mu pelu aniyan bi ase fe ki ise na ma sise lara wa e.g (onmo nla, iriran,asotele atibebelo)
Ao gbe eko na mu lesekese ao mu oti seaman (dry gin) lelori
Ao mafi tesibiu na korun ti aba fe ye ise wo fun eniyan ao ma rii gbogbo nkan tiwon bawa
BIBELI:- Ao somo oke kan ao ma bani gbolohun, ti aba fe fi ye ise wo ao sofun wipe koyisi apa otun abi apa osi yosi sebe, (odara lati fi ye ise wo, tabi ole, lati travel, ati bebe lo
Akiyesi- tesibiu na ko gbodo kan le ooooooo.
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...
-
ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA. Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie ag...
-
ORUKA ANASARE AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO N...
-
Pdf awon acct mi fun ebun odun Moma yonda re fun gbogbo ile ni 1000 pere Sugbon akojopo agbara yoruba nikan ni 2000. 07080271083 Ori...
No comments:
Post a Comment