IFA OGUNDABEDE
O. O
O. O
O. O
O. OO
PSALM RE NIYI- IBA 3X - IFA BESODE 3X ORUNMILA BESI IDALE 3X ADIA FUN AJETELUWA , IFA MI O BATELUWA KIAKIA OBA TEDALEWA SASAWARA, IFA MI O BAWA BAMI WA OWO NLA NLA LOTUN, KIO BAMI WA OWO NLA NLA WA LOSI KIO GBEWA FUN EMI L OMO L,, KI NRI MUSE OHUN RERE LAAYE MI, IFA MONI O TO GE GE KIO WA SILEKUN OKUN-OLA TEMI FUN MI LONI NI KIAKIA NITORI PE ORUN AKERENGBE FINSILEKUN OLA FUN ONILE, ORI NI EWURE FIN RU ERU OLA FUN OLOKO, BI ASIRI ALAJOBI AIYE KO BABO ALAJOBI ORUN NI NBO LASIRI .......... ATI BEBELO ETC
LILO RE - ODINDI IGO EJE ALUJONU KAN LAO GBE TI ISE YI..TI AO FI MALO DIE DIE.. WALAHI KIO TOPE TWO WEEKS.. ENITI NLO IFA YI GBODO GBAA OWO NLA GIDI..
AKIYESI_ ENIKENI TIKO BATO 33YEARS UPWARD KO GBODO LO ISE YI OOOOOOOOOOO.. EWO NI.
Wednesday, August 28, 2019
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...
-
ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA. Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie ag...
-
ORUKA ANASARE AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO N...
-
Pdf awon acct mi fun ebun odun Moma yonda re fun gbogbo ile ni 1000 pere Sugbon akojopo agbara yoruba nikan ni 2000. 07080271083 Ori...
No comments:
Post a Comment