Friday, November 8, 2019

BLACK FRIDAY BONUS
07080271083 Buy 1 pdf per 500 naira from 08/11/2019 till 29/11/2019

Saturday, September 7, 2019

Agbaraigbaani facebook platform

E bami pade ni facebook platform mi https://m.facebook.com/groups/462551627571483?refid=27&ref=opera_speed_dial

Ajeogun ebora

Ogun ajeogun fun eniti ogun kn sise lara eeeeeee Ewe........ Eso ....... Aoo lo papo ti aba tilo papo ao fi se eja aro gbigbe meta je lepo niyo Leyin tu aba jetan ao lo wo aso wa nitori ihoho lama je ise na Leyin taba wo aso tan enikan yio wawa wa yio sowipe ohun bere enikan toba ti sobe e sowipe kosi nile leyin ti enina balo tan Ara yin yio segiri bi igba ti ina ba gbe yin Leyin ojo keta lato ni anfani lati sunmo obirin ooo Ise yi daju gan, Fun ekun rere alaye - 07080271083.

Thursday, August 29, 2019



                        OGUN AWISE
Ewe ina ff 7, ewe agbado ti eranko pa sile  ao ge si ona 7, irun iro, ao fi eje oromodiye lo won papo ao kosinu iwo etu ao ma fi ahon tola ti abafe soro
Ohunkohun tu aba so beni yio rio


                   OGUN ASEGBE/AJEGBE
Ewe ira, taba gidi, alubosa elewe, eku asin kan, iseta ao lowon po ao da sinu adin ao ma laa


(b).  Orogbo ki o po atare  kio po die ao ki sinu apola eran etu; ao yan yio gbe ao lo po fun lila.


                  ONMO TODAJU
Ewe isepe agbe, layonbere kan, ikode kan, eyo atare meje, ao ko won sinu layonbere ao fi aso funfun  we ao ran ni onde awo tio ba wun wa  ao ma fisi idi ni asiko tio ba wun wa pe afe mon nkan tabi afe wo ise fun customer.



                   ONMO IRIRAN  OUNJE
Ori ako alangba kan, omole kan, atare kan, ikode meta, ao bu ijalo ti nwon koja ona die ao jo gbogbo re papo ao sin ni gbere yi orun owo ka ati isale oju mejeji,ao ma sin ni osu meta meta Odaju




                     OSE OWO TODAJU (money)
Ewe taba tutu, eru alamo pupo, epo obo die, ao gun pomo ose ao ko sibi kan  ao ma buwe oda pupo fun awon oloja.










                                  

                     OSOLE OWO TODAJU
Odidi olongbo kan ao fi tele ape tagiri meta, ao ge kekeke, ap kole lori eepo obo tofe to atelewo meji ao pa pepepe, ao ko le lori ao fi odidi atare kan le ao wa ko ewe ola ti yio po ao kole lori ti yio bo ao wa ma fi oti lo lararo (shinapp) jijo ni ogun yio


                    ASEJE OWO TODAJU
ewe alukerese,ewe aje sefunsefun,epo ijebo,iyere.ao lo gbogbo re papo.ao fise edo malu je lepo niyo.(16)ni aoge edo yen si.ti oba jinnan,ao so sori osuka.awa fi iyere osun tefa ejiogbe,aope ofore si,awa dasinun obe yi ao wa je.OFORE:tente ni osu nle3×,irawo sasa nise elegbe leyin osu3×,adeyinka pele omo oloja3×,oke pele omo afegbe tinan3×,ayidi nsawo kokofa,ayidi nsawo koko ogun,odifafun orunminla nigbati awan mererin nba se ota,wan ni onifa kan kan koni wa


                OGUN OKIKI TODAJU
oga gbigbe3, ewe ewuro oojo, tio po die atare odidi kan, ao jo papo ao lo ao wa mala ao ma mu oti le lori.




                                                 EBU OWO
Oju maalu 16, obi gbanja 16, orogbo 16, atare odidi 16, obi abata 16, afomo botuje ff, Gbogbo iran owo patapata, (1000, 500,200,100,50,20,10,5) ao mu awon eroja yi nikakan sinu ape titi yio fi tan, ao wa fi afomo lapalapa bo lori ao jo papo ao mafi omi lo lararo ojo aje (Monday)

Wednesday, August 28, 2019

Pdf awon acct mi fun ebun odun 
Moma yonda re fun gbogbo ile ni 1000 pere 

Sugbon akojopo agbara yoruba nikan ni 2000.
07080271083

Orisirisi ni 
awon pdf yi ooo

Eyi teba fe ninu won

1. Agbara igbaani 1
2. Agbara igbaani 2
3. Akoni odua
4. Majemu tuntun
5. Akojo agbara yoruba
6.iwosan eda
7. Iwulo psalm 1&2
8. Iwulo ewe pelu oruko won
9. Seven book of moses
Ati bebe lo


OLUGBOHUN TODAJU 
                                                     
Ako ewe mereerin (ewe ina ewe esisi ewe aragba ati ewe oloyin) aogun po mose dudu aofi emu aila pelu oguro aila po papo pelu oti schinap po Papo dada aofi oga aye ati eja ojiji aye kan tele iho malu yan aowa ko ose yan lelori aofi aso pupa bo lori ao we mo lara aomasin aso pupa yan loju re ti abafelo ao kan ma se hahaha lemeta si ni aose adura ikan ti abafesi

   ORUKA ANASARE
AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA  TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE  AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO NINU IGBE NA TO BA JASILE AO FI NKAN KO AO LOJO PAPO AO DASI INU EPO PUPA INU EPO PUPA LAMA TIMA MU ORUKA NA.



                                                                        OGUN IJAKADI
Ose dudu, alubosa elewe , irun eyin olongbo dudu, tiko ni awo kankan ju dudu lo oruka ogun meji 2, koro atare meje, ao wa gun po ao wasu rugudu ao fi oruka na bo ni arin, ao wa fi aso akisa di ao lofi ha palapolo iganna (ogiri alapa tio la enu sile) fun ojo meje , ao lo mu odi lilo

                                                       IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU
 Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu lofinda eyikeyi ao maa fi paa oju tabi gbogbo ara. Awon Enia yio maa ni ife waa pupo


ATONA/OUNMO 2 IN 1

Bibeli tuntun kan, tesibiu funfun tuntun kan, ako eye ega kan, jigi tiofo si oju ona, atare odidi kan.

SISE:-  Ao mu candle funfun kan si arin bibeli ni psalm 91 ao tun mu candle blue kan si arin psalm 19ao fi amure na dini gbogbo ara ao wa fi kokoro(key) kan sin i ori nibi ti ati ma nsi bibeli latika, ao sese wa dini owu funfun dele ti  bibeli na koni han sita rara

Ao sese mu blade tuntun ao fi lofa tinuteyin ilekun  ti ama nsi wole dada (ilekun gbagede)
Ao lopo mo jigi oju ona na aodasi oto,
Ao sese wamu eye ega na oleje tutu tabi gbigbe, ao jusi inu ikoko tuntun pelu atare na ao jopo dada leyin ti o ba jotan ao jeki o tutu ao wa ju tesibiu na sinu re,  ao gbe ikoko na pamo titi di ago kan oru (1am)

LILO:- Ao ra eko tutu, ao da awon ebu mejeji na papo ao ropo dada ao fi fo eko na mu pelu aniyan bi ase fe ki ise na ma sise lara wa e.g (onmo nla, iriran,asotele atibebelo)
Ao gbe eko na mu lesekese ao mu oti seaman (dry gin) lelori
Ao mafi tesibiu na korun ti aba fe ye ise wo fun eniyan ao ma rii gbogbo nkan tiwon bawa
BIBELI:- Ao somo oke kan ao ma bani gbolohun, ti aba fe fi ye ise wo ao sofun wipe koyisi apa otun abi apa osi yosi sebe, (odara lati fi ye ise wo, tabi ole, lati travel, ati bebe lo
Akiyesi- tesibiu na ko gbodo kan le ooooooo.

IFA OGUNDABEDE

O.    O
O.    O
O.    O
O.   OO

PSALM RE NIYI- IBA 3X - IFA BESODE 3X ORUNMILA BESI IDALE 3X ADIA FUN AJETELUWA , IFA MI O BATELUWA KIAKIA OBA TEDALEWA  SASAWARA, IFA MI O BAWA BAMI WA OWO NLA NLA LOTUN, KIO BAMI WA OWO NLA NLA WA LOSI KIO GBEWA  FUN EMI L OMO L,, KI NRI MUSE OHUN RERE LAAYE MI, IFA MONI O TO GE GE KIO WA SILEKUN OKUN-OLA TEMI FUN MI LONI NI KIAKIA NITORI PE ORUN AKERENGBE FINSILEKUN OLA FUN ONILE, ORI NI EWURE FIN RU ERU OLA FUN OLOKO, BI ASIRI ALAJOBI AIYE KO BABO ALAJOBI ORUN NI NBO LASIRI .......... ATI BEBELO ETC


LILO RE - ODINDI IGO EJE ALUJONU KAN LAO GBE TI ISE YI..TI AO FI MALO DIE DIE.. WALAHI KIO TOPE TWO WEEKS.. ENITI NLO IFA YI GBODO GBAA OWO NLA GIDI..
AKIYESI_ ENIKENI TIKO BATO 33YEARS UPWARD KO GBODO LO ISE YI OOOOOOOOOOO.. EWO NI.

OGUN FAMILY PLANNING.ODUN KAN ATI OSU MEJI LOMA LO LARA:


ESO IYALODE FUNFUN AO yo funfun inu e kan ama lo bi tablet ,to ba di ojo keta ti ati lo ama mu agbo jejdijedi OMA bere ise ni ojo keta ko ni wahala kankan be niko si (repercussion) odunkan leyi fin sise
nigbati obinrin ba nse nkan osu,ao fi owu soju arawa moju ojo keji ao jeki owu yipo die,ao wa yo laro ojo keji,ao wa ja ibi ti eje yen ba soak dada ninu owu yen,ao so iyi toku nu,ao wafi iyiti a ja yen sinu efe owu miran,ao fi oko atare kan si legbe,ao di niko bere pelu owu dd ati ff,ao wa ju sinu igo cream to de dada gan,ao wabu adin si ninu,loba pari ooo,hmmmmmmmm bi ogo ti nje ti Olorun onitoun kole loyun.

ERO RE- ao shi igo adin yi,ao danu,ao yo ogun yi,ao tun ka sototo,ao ko danu,lehin eyi ti a ba sunmo okunrin hmmmm,a nbo waje rice


IPESE FUN OHUNKOHUN

Eran maalu ekiri kan ao so fun awon eleran kiwon bawa ge rubutu ko tobi die ao wa fi iyereosun tefa osameji soju opon ifa aofi ekiri eran yi siwaju odu yen aofi obi alawe merin kan si eti opon ifa naa ao wa pe ohunre sinu odu yen Lenin naa aofi eran ko ifa naa aofi sinu awo ipese tuntun kan ao bu epo lelori aofi obi yen bere ibiti won yio ti gba ipese na ni adugbo wa Toba di aro ojo keji aolo mu awo ipese yi wale lati tun fi se ipese yi nigba miran

OFORE:Ake kaaka wolu3× Abirin kakaka wolu3× A gbe ori iroko ke kakaka3× Ibiti edarisi ni edari si3× ibiti e pin jeki si lepin jeki3× Eyin ni igba Erin ri tiwon nfi eyin lu eyin omo opere opere3× Eyin ni igba efon ri tiwon nfiiwo lu Iwo omo ogbangandanran ogbangandanran3×Eyin naa ni igba olopere ri tiwon fi nfo janpe janpe kalu3×Ewa ni kinni igba Erin ri tiwon fi nfi eyin lu eyin omo opere opere Eni kinni igba efon ri tiwon fi nfiwo luwo omo ogbangandanran ogbangandanran Ewa ni kinni igba olopere ri tiwon fi nfo janpe janpe kalu Ero!ero!! Ero!!! Seese lodifa fun koowe ajedo eniyan mabi Aje oronro masinto Eewo ni aje ko gbodo pa omo koowe je ki aje mapa emi lol ooo Kiwon lo Lana rere gbogbo owo nlanla fun mi lati oni lo nio Nitoripe agbadikaka3× loruko tanpe ifa orunmila ninu gbogbo eye to nfo radiradi loju orun eyin iyami osoronga ati okanlerugba irunmole loba olodumare pinhun lode orun Won ni ki olodumare fowo mu ode orun ko yonda ile aye fun awon ni kiakia olodumare fowo mu ode orun osi yonda ile aye fun yin Nigbati e dele aye tan eyin iyami osoronga tunwa ba orunmila pinhun wipe ki orunmila fowo mu aaro ati osan Awon ni awon ni oru won niti orunmila bati pese fun awon loru awon yoo mase gbogbo nkan toba fe fun laro ati losan orunmila wa biwon lere wipe kinni ohun ipese naa won niki orunmila mafi eran abeje malu ekiri kan pelu iyereosun pese fun awon toba ti pe oruko awon awon yo mase gbogbo ohun tobafe fun Ipese ti eniki orunmila se lojo kinni anaa ni emi L omo L se fun yin loni yio Ti o base wipe lododo ati lotito leba nbe lode isalu aye yi ki ewa lo pese gbogbo ohun ti mo bere funmi ni kiakia bayi oo adura ohun ti abafe kiwon se fun wa ao gbe losi ibiti won tife gba.....


WEGUN WEPE TO GBONA

Elo wa egbo tude tutu ati ewe re,egbo iyalode funfun die,pupa die,ewe iyalode funfun ati pupa die die,epo oboh die ewe ajeobale die tobaje pe obirin lafe se ise yii fun ata wewe adaiyeba meje tobaje okurin ni ata mesan eo pa awon egbo yen peepepe ao yo igi inu re danu ao gun epo arawon po mo awon ewe yen pelu ata ao fi ewe ejirin wewe se kainkain fun,wiwe lodo to nsan fun ojo meta lerawon pelu fifi epo pupa pa ara.

AMUDO MAJIYAGBE



ALAGIDI OBIRIN

EYIN IBILE TI O MO DAADA AO LO JA EWE  .................. TUTU AO SA EWE NA KIO GBE AO WA LO DAADA TI YIO KUNNA AO WA LU EYIN NA LORI AO DA SI A O WA NIKI AWON ALAGBEDE BAWA RO ORUKA KIWON MA KIBO OMI OOOO
AO JU ORUKA NA SINU EYIN NA AO FI LAILON DI AO SE EYIN NA TOBA TI JINNA AO YO ORUKA NA AO JE EYIN NA AO WALO  SA ORUKA NA SIBI TI KOTI SI ORUN AO WA KI ORUKA NA BOWO MU OBIRIN DANI LORUN OWO

EWO -AO GBODO JE EYIN ABO MO OO
AND ENI TOJE EYIN LOMA BA SISE OOO

FUN DETAILS ISE YI TIA YO KURO 1000 NAIRA PERE LEMA FI GBA.

Acct no yi lema san owo na si fun ekunrere alaye ise yi texted okay ni ise yi gbiyanju re ko fun mi labo
07080271083
5577324011
Kilani opeyemi
Fcmb bank

OMO EGBE OTITO.

Identity card lati di omo egbe agbara igbaani Facebook &whatsapp platform
Contant- 07080271083

ORO NIPA IRAWO ATI OHUN TI O BAA IRAWO OLUKALUKU MUN LAYE O po Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe dandan ise bayi bayi ni kio se , oko bayi aya bayi ni kio fe


Fun ekun rere alaye
Pelu awon ise adimula

Ekan simi fun PDF ATI IWE AGBARA IGBAANI SEASON 1&2

BONUS  (IWE- 5000
PDF        ( 2000

NORMAL PRICE ( IWE 8000
PDF 4000

ASEJE ASIRI BIBO NI KIA KIA

ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA.

Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie agric meta lepo niyo, tio bajina ao so kale Ao je kio tutu ao Se adua si, ao waje Walah talah EMI OPA FITILA MOSO TEMI MO DENU DURO NA KI ADABA MI MA DAWO ISE DURO

ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER

Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...