OPA FITILA BLOG (Agbara igbaani)
Monday, December 2, 2024
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori fun okunrin, mefa loke mefa ni isale fun obirin ao se jina lai fi omi si ao se jina toba jina ao so si ori osuka kan ao se adura si ao bo eyin na ao je pelu adura owo leyin ojo keji o bere ise
ASIRI BIBO TODAJI
Tagiri nla meta ao ha aje ara re si ibikan ao lo aje na pelu ata ijosi meje tabi mesan fun okunrin ao fi se eja aro tabi igbin tabi eyin ibile je, pelu adura ao mu fanta mineral tutu si. odaju
fun ibere message on Whatsapp 07080271083
fun awon iwe asiri lolokan ojokan
Thursday, February 25, 2021
Friday, July 10, 2020
Call for your castor seed at low price
@
Twins T Home of heal
And also contact for other treatments
Spiritually & medically
Eso Castor ti o sise fun didena omo Bibi larin loko laya
Ti o Dara fun ago ara wa
Eyo kan fun odun kan ni eso na fin sise
Contact us for your own fast fast
Hotline_ 08066780585
Sunday, May 10, 2020
Saturday, September 7, 2019
Agbaraigbaani facebook platform
E bami pade ni facebook platform mi
https://m.facebook.com/groups/462551627571483?refid=27&ref=opera_speed_dial
Ajeogun ebora
Ogun ajeogun fun eniti ogun kn sise lara eeeeeee
Ewe........ Eso ....... Aoo lo papo ti aba tilo papo ao fi se eja aro gbigbe meta je lepo niyo
Leyin tu aba jetan ao lo wo aso wa nitori ihoho lama je ise na
Leyin taba wo aso tan enikan yio wawa wa yio sowipe ohun bere enikan toba ti sobe e sowipe kosi nile leyin ti enina balo tan
Ara yin yio segiri bi igba ti ina ba gbe yin
Leyin ojo keta lato ni anfani lati sunmo obirin ooo
Ise yi daju gan,
Fun ekun rere alaye - 07080271083.
Subscribe to:
Posts (Atom)
ASIRI BIBO OWO FUN DECEMBER
Ewe iyalode funfun 14 fun okurin 12 fun obirin ao to mefa si isale ape ao si oju re soke, ao fi eyin adiye agric meta si, ao fi meje bo lori...
-
ASEJE BIBO ASIRI NI KIA KIA. Ao wa ewe tangiri oojo 16, ao wa ewe ola die, ao wa iyere 16, ao lo Gbogbo re papo, ao wa fi din eyin adie ag...
-
ORUKA ANASARE AO LORA ORUKA KAN,AO MA SO AJA TOFE YAGBE AO MA SOO AKO AJA TOFE YAGBE AO PARIWO MO AJA NA TI IGBE NA BATI FE JABO N...
-
Pdf awon acct mi fun ebun odun Moma yonda re fun gbogbo ile ni 1000 pere Sugbon akojopo agbara yoruba nikan ni 2000. 07080271083 Ori...